lirikcinta.com
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

jesu oba - tosin koyi lyrics

Loading...

intro:
ok, i mean
i’ve got silky on the beat
actually, i’ve got this nice song
i want you all to listen
yeah, alright

prelude
ará ẹ wá gbọ́ . [everyone, listen up]
ìròyìn rere ni mo múwá . [we bring glad tidings]
ará ẹ wá gbọ́ . [everyone, listen up]
ìròyìn rere . [glad tidings]

everybody say yeah, yeah
(yeah, yeah)
yeah, yeah
(yeah, yeah)
say yeah
(yeah)
yeah
(yeah)
yeah uh…

verse 1
ibanuje d’ òpin . [sorrow is abolished]
(l’aiye wa) . [in our lives]
ikú d’ òpin [death is abolished]
(l’aiye wa) . [in our lives]
ẹ̀ṣẹ̀ d’ òpin . [sin is abolished]
(l’aiye wa) . [in our lives]
àìsàn d’ òpin . [sickness is abolished]
(l’aiye wa) . [in our lives]

prechorus (x2)
nitori, ẹni tí a’ reti ti dé . [because, the expected one has arrived]
(ọ dé, o dé) . [he is here, he is here]
olùgbàlà aráyé . [the saviour of the world has come]
(ọ dé, o dé) . [he is here, he is here]

chorus (x4)
jésù ọba! . [king jesus]
(ọba, ọba awọn ọba) . [the king, king of all kings]

verse 2
imagine a virgin giving birth to a child
imagine the son of god here on earth

for bethlehem
(beth-le-he-mu)
mary born pickin o
(born pickin o)
three wise men dem
(three wise men dem)
dem dey find the king o
(dem dey find the king)

prechorus
ẹni tí a’ reti ti dé . [the expected one has arrived]
(ọ dé, o dé) . [he is here, he is here]
olùgbàlà aráyé . [the saviour of the world has come]
(ọ dé, o dé) . [he is here, he is here]

chorus
jésù ọba! . [king jesus]
(ọba, ọba awọn ọba) . [the king, king of all kings]

refrain
(ọba, ọba ah) . [the king, the king]
(ọba, ọba) . [the king, the king]
(ọ dé) . [he is here]

(ọ dé) . [he is here]
(ọ dé) . [he is here]
(ọ dé) . [he is here]
(ọba, ọba ah) . [the king, the king]

(yeah, yeah)
(yeah, yeah)
(yeah, yeah)

Random Song Lyrics :

Popular

Loading...