taba nso - tope alabi lyrics
tan ba so, ke gbo (ke gbo)
tan ba wi, ke gba (ke gba)
tan ba so, ke gbo (ke gbo)
tan ba wi, ke gba (ke gba)
la’alu o le fun ni igi ishana, ko ma fi gba koko
tan ba so, ke gbo (ta ba mi so o)
tan ba wi, ke gba (ehh ehh eh)
tan ba so, ke gbo (komo eniyan lati)
tan ba wi ke gba (ke gba)
la’alu o le fun ni igi ishana, ko ma fi gba koko
ni bi ti o se lo ti fe ma je
agaga to ba fun o ni epini
afi gba egberun
esu ko je fun ni fila laye
ko ma gba ori lowo eni o
tan ba so, ke gbo (ki lo a dasi)
tan ba wi, ke gba (abi eri ise esu)
tan ba so, ke gbo (ahh ahhh ah)
tan ba wi, ke gba
la’alu o le fun ni igi ishana, ko ma fi gba koko
ki olorun ko gba eni lowo wan
awan gbaoromidieleru
wan a shanu keke, wan tun pani lara
e fi oro loni ni iwan ba, ke ma ba kolu eluda
tan ba so, ke gbo (ahhh ahh ah)
tan ba wi, ke gba (esu o ni kan titi)
tan ba so, ke gbo (owo eledua ni gbogbo re wa)
la’alu o le fun ni igi ishana, ko ma fi gba koko
ni bi ti o se lo ti fe ma je
agaga to ba fun o ni epini
afi gba egberun
esu ko je fun ni fila laye
ko ma gba ori lowo eni o
ehh ehh eh
to ba fun ni ni ediye
afi gba odidi eyan
tan ba wi o, ke gba
tan ba so, ke gbo (tan ba wi kegbo)
tan ba wi, ke gba (ehh eh eh)
la’alu o le fun ni igi ishana, ko ma fi gba koko
tan ba so, ke gbo (ke gbo)
tan ba wi, ke gba (ke gba)
tan ba so, ke gbo (ke gbo)
tan ba wi, ke gba (ke gba)
la’alu o le fun ni igi ishana, ko ma fi gba koko
Random Song Lyrics :
- fck tht! - time just kills lyrics
- жaлкo дик - krasav4ik_229 lyrics
- cold heart winter - ynkeumalice lyrics
- i shall wear a crown - eshon burgundy lyrics
- afterlife - tora lyrics
- абсент (absinthe) - dnlwrstn lyrics
- la barca non va più - orietta berti lyrics
- drecksgeschwätz - permanent marker lyrics
- superstition (apple music sessions) - 49 winchester lyrics
- summer ends - so moody lyrics