lirikcinta.com
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

omo ranti - tope alabi lyrics

Loading...

omo ranti o
omo ma gbagbe omo eni ti iwo nse
igbala ni eee asiko imo re tide o

omo magbagbe eleda re
omo ranti
omo ranti ooo omo ma gbagbe omo eni ti iwo nse
igbala ni eee asiko imo re tide o
omo magbagbe eleda re
magbgbe eni ti seda re
ile ti a fi tomo ire ni owo o
omo ti o la farada yoo san eje fatunbotan
igba lodo hun ni laye
agba fere kan odo na o
tara sasa omo lopin re koda
sekia nigba owuro omo ranti o
omo ma gbagbe omo eni ti iwo nse
igbala ni eee asiko imo re tide o
omo magbagbe eleda re
tanba ba owo wi to ba n warunki
awon agba lomo ta oko agbele tako ta o
sasa lomo ta oko o iwon lomo ton gboran o
omo ma pami to ba se die yoo domo mapara re
oti to jubo lo se yan eyi ofeyan yoya
b–ba ranti
oniba lo so bai loruko
oun to ba perare
opo omo ti bayelo won ti kasa idakuda
okunrin o le dobale kagba debi obinrin akunle ki enitoju
oro alufansa lenu won
awon omo nibi niran
aye n baje ema sope on dara
ogede n baje ema sope on pon
suuru baba iwa o kiise todo iwo yi mo o
odo aye ti towo bobo kubo afaitan bene ten mami bi erin lokun
omo ti o janu lenu omu to wa n femi famu owo o fe di borokinii lawujo
moto atata ile alara goolu iyebiye lo fera o
ema gbagbe aje iweyin to pelede ijosi iku ojiji dede lo fiyin sere
ma femi e toro fun satani jowo ronu o omo ranti omo ma gbagbe eleda re
be o ba gboro obi o te o tun gbo tolorun
dede iku n be lode iku ma n be lode on polowo eya daakun egbooro mi keya gbotebi yungba yungba ayiyin ni
ke ma pa obi yin lekun me ma sowon dagan ale yungba yungba ewu o ba nilara
o ni le jakara ore ko tun mu dani
esin to sare irun ni orun gbeyin
ole ririn ajo kotun wa nile o ko ma lo jepe ko ma lo kuku
wa keni koto keji dandan ni aikawe aigbeko ofeyege elere egele alera efe
won fe gba okunkun dalagbara koni le lora emi rerara ayobe a kun ebi alapata o fe jere re sorun apadi ni ranti eleda re nigva ewe re jesu feran re nigbati ojo ibi ko tii de ogo olorun lo je mamaje kesu o yoo subu
fogo olorun han lana gbogbo
maje kohun aye tan o pa ojare
ki lelere eleda re ton pe o
omo pada ba eleda re laja
to ba le yii pada ko satunse aye re
egbegbe yoo gba ye re lagbala
ma wobi okunkun to ti worin jina pada o le gba o se kia
edegbede yoo roo o lagbala
ojo iwaju re yoo ma da
ma beru eni olorun le pa
eni to tooni gba ni o sa waba
edegbede yoo roo lagbala
eto to fisile fun o ju wura iyebiye lo
jesu duro lenu ona on duro on pe o o omo wole wole wole

Random Song Lyrics :

Popular

Loading...