oluwa nbe funmi - tope alabi & iseoluwa lyrics
ah bogun aye ti po to o
oluwa mbe fun mi
aah biji aye tin ja to o
edumare mbe fun mi
boti wu ko le to
boti wu ko ja to o
ko ni le mo mi o
edumare mbe fun mi
ko ni le mo mi o
edumare mbe fun mi
mo lo oluwa toto gbo gbojule
mo ni jehovah tose fe hinti
agbokanle emi ti ko le ye lai
edumare mbe fun mi
edumare mbe fun mi
ma ko ja mi olugbala mi o
gbo adura mi
gba ti wo mba pe elomiran
ma see ko ja mi
bogun mba dide bi omi
mo duro lori kristi
lori kristi apata mi
oba ayeraye
ko ni le mo mi o
edumare mbe fun mi
ah agbara to gbe le aye ro
iwase gbogbo eda
ohun kan soro se fun
oso egun gbigbe di alaye
oso egun gbigbe di alaye
aah bi aye yii ti fe to
egun yii aye po
bo oju eda se le gun to
ika aye finu sinmi
ki aye ko koja ori
imo owo lekosi
ere lewe iye
kosi beru fun omo olorun
ere lewe iye
kosi beru fun omo olorun
oda iji ro oda keje
oda oko ota isreali so mi
ofidi je odidi oba
agbara re wa si be
agbara re wa si be
eni to rin lori gbi omi o
ipa agbara
oba to mo omo eda gbogbo
ka sha ini mo bi inu okun
ibi to tin ru bo wa
ati ibi ton ru lo
koni ru de odo mi
baba mbe fun mi
koni je oru de odo mi
baba mbe fun mi
oluwa ni agbara mi
aya eni ti o fo mi da
ogbagba to gbe mi lejika
iye apa re igbekele mi ni
igbekele mi ni
ooooooooo
akoda aye
ooooooooo
olu ogun orun
oni ki ji pa awolo jagun ajaye
ke ru ke ru re bo wa le
oni ki ji pa awolo jagun ajaye
ke ru ke ru re bo wa le
ooooooooo
akoda aye
ooooooooo
oluogun orun
oni ki ji pa awolo jagun ajaye
ke ru ke ru re bo wa le
oni ki ji pa awolo jagun ajaye
ke ru ke ru re bo wa le
Random Song Lyrics :
- fortnite virou hentai - mc maha lyrics
- upon a life i did not live - indelible grace music lyrics
- tattooed scars - bile lyrics
- living on the stage - china lyrics
- besser ohne mich - simon will lyrics
- reason to forgive - october project lyrics
- jealousy is a familiar friend - reese lansangan lyrics
- damaged - lani rose lyrics
- mamacita - noah lunsi lyrics
- glaubst du - n p s t c lyrics