lirikcinta.com
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

ramadan - tolibian lyrics

Loading...

[chorus]
saari, saari ti to muslim ẹ dide n’lẹ kẹ jẹun o
ehn, lọsan ramadan
oju mi ti ri lọsan ramadan

[post*chorus]
b’ọn gbounjẹ wa mi o ni le jẹ (why, why, why)
b’ọn gbomi wa mi o ni le mu o
agba to lomi ninu o ki n pariwo mo ti n gbawẹ

[verse 1]
awẹ tan, oju tajọsan
awẹ tan, oju tajọsan
irun ti to ki ẹ lọ bori
saari ti to jẹ o, ah
ẹ dide nilẹ o, ẹ lọ se jijẹ o
ẹ dide nilẹ o, ẹ fi’gbo silẹ o
ẹ dide nilẹ o, ẹ lo se jijẹ o
ẹ dide nilẹ o, ẹ fi’gbo silẹ o

[chorus]
saari, saari ti to muslim ẹ dide n’lẹ kẹ jẹun o
ehn, lọsan ramadan
oju mi ti ri lọsan ramadan

[post*chorus]
b’ọn gbounjẹ wa mi o ni le jẹ (why, why, why)
b’ọn gbomi wa mi o ni le mu o
agba to lomi ninu o ki n pariwo mo ti n gbawẹ
[verse 2]
ẹ ye fa baki lọsan ramadan
ẹ ye gboloṣo lọsan ramadan
ẹ ma ṣe ṣaṣe ninu ramadan
o ṣi tun wẹṣẹ ninu ramadan

Random Song Lyrics :

Popular

Loading...