ascura clear - t-flat lyrics
intro….
i’m sheliroy…, kazy s-xy in the building…. oh no,,no no know,, acronym tflat (tflat…verse1)
okay naa
i dey on ma level (level)
on a higher level (level)
level tó ju level
kẹ́ má lọ̀ b-ssi fún mi trebble
mó gbé ‘na jẹ́ mó tà
mi o lẹ nánímọ̀tà
ascura rí mì o yá
ma pẹ pasta fún mi b-tter
ọ̀mọ̀ yẹ́n wà okay (ascura)
but ọ̀mọ̀ yẹ́n bad oo (ascura)
something wey bad fit light
the cash so throw am for trash oo (ascura)
la-ti-fa-do-mi, la speedometer
ka-da-ra-mi, kò lé rí gbà
égbè mágbé, éèláà ti báà
but i’m fully loaded anti- -(ascura)
thu 8:04am
1st hook by tflat
bọ̀la má bo’ọ̀la mi mọ̀lẹ̀
ṣádé má shade mi (má change mi)
blessing lo ni ki ẹ́ lọ̀ kọ̀ lẹ̀
ìré ni ti tẹ̀mí…… (2x)
2nd hook by tflat
(ascura) égbé màá gbé
málọ̀ gbé yẹ́n lo, yellow ni
(ascura) nkan ti o dáni mágbe
kai! mágbé sẹ́ (ascura)
no worry na, no yawa anti-ascura is here (ascura)
múlẹ̀ fún áwọ́n ọ̀mọ́ iràwọ̀, no gutter
:sheliroy…verse2)
ti nbá bu garri só mi
mó má n duro five mins
kowu ko le yomi
tẹ́lẹ́tẹ́lẹ̀ ojú ti ri ya
ni sin mo di ẹ́ni ti
o n fi hennessey jẹ́ suya
see me chilling in ma lamborghini
they see me dabbing hann
designer gucci gucci, see me cruising in ma maserati hann….
bọ̀lá má bọ̀’lá mì, (ascura)
koṣi má lọ̀ kó bá mì (ascura)
mi o sín gbẹ́rẹ́, mì o lo gbékudè
má lọ̀ mú mi ṣéré oo (ascura)
baby oya come to daddy (ascura)
spending naira pound sterling (ascura)
ṣo mọ̀ sodom, ṣo mọ̀ gomorrah
call me the living dragon… (ascura)
1st hook by tflat…….
bọ̀la má bo’ọ̀la mi mọ̀lẹ̀
ṣádé má shade mi (má change mi)
blessing lo ni ki ẹ́ lọ̀ kọ̀ lẹ̀
ìré ni ti tẹ̀mí…… (2x)
2nd hook by tflat
(ascura) égbé màá gbé
málọ̀ gbé yẹ́n lo, yellow ni
(ascura) nkan ti o dáni mágbe
kai! mágbé sẹ́ (ascura)
no worry na, no yawa anti-ascura is here (ascura)
múlẹ̀ fún áwọ́n ọ̀mọ́ iràwọ̀, no gutter
(kazy s-xy…verse3)
wooo oooyeeeah wowo iyeiye..
see 1kazy s-xy, saintsami j-paa, mule gutter, eyan saintsamiganger
kazy s-xy mori ‘ré, mo fẹ́ ko ascura
mo ya tètè sárẹ́ lẹ́
kazy s-xy mori ‘ré, mo fẹ́ ko ascura
mo ya mo ya sárẹ́ lẹ́
mo ji ‘ya t-ti ki n to di akuna takasi
akuna takasi eeeee
àbẹ́nì o ni pangbẹ́ (ascura)
yeh! mọ̀ gbẹ́ lọ̀ (ascura)
mo fẹ́ rí ẹ́ mọ̀ sẹ́, dákun mámà ko bá mi (ascura)
àbẹ́nì o ni pan (ascura)
dákun mọ̀ gbẹ́ lọ̀ (ascura)
mi o ṣé do again
yehi yeh i yeeh eee…. (ascura)
(outro by tflat)
agba, eyan 4ourty bábá
kèkèré ti o ṣé jigbé …… (40million$)
olorí àwọ̀n anti-ascura fún ra e
langobell, ọ̀lamidẹ́ pure water…… (i see you)
kelanisurprich, kelanikelz
Random Song Lyrics :
- deus não erra - jamerson gama lyrics
- gegen die objektiven - wolf biermann lyrics
- running out - irma vado lyrics
- courage in hand - entropy lyrics
- вода (water) - floodyus lyrics
- i have confidence (demo version) - marni nixon & irwin kostal lyrics
- монгольская степь (the mongolian steppe) - nautilus pompilius lyrics
- zero to sixty - big homiie g lyrics
- sjarmør (beepolar) - problembarn lyrics
- ysm на деле (ysm in practice) - yasmi lyrics