oyinbo - small doctor lyrics
ain olosho mu standing
ain ain ain arara
na who do the beat
dresan the royal highness
call me small doctor
akeweje oganla ain
ewa wo oyinbo to se koste
bo oyinbo ba ku re
ko ni sun re
awon oyinbo niba aye je baba o
won je a mo adelebo solomo ge
toba ro owo mu rubber mo onirin wo koko mo
won a si fi eyin mejeji ko ra won
awa okunrin awa o ma ronju
a o ni mo pe eko to ti ro lo tun pon
ani ko oloun shanu eyan ni ain
odun yi le ni chance mo
gomino wa ti tun shey ofin tuntun
o ni to ba di january 27
won gbodo ko koste wale yi mo o
ka pada si komu alapo tijosi o
iseyin la mo oyon to wa pangolo
ani ko oloun shanu eyan arara ain
call me small doctor
akeweje oganla ain
ewa wo oyinbo to se koste
bo oyinbo ba ku re
ko ni sun re
awon oyinbo niba aye je baba o
won je a mo adelebo solomo ge
toba ro owo mu rubber mo onirin wo koko mo
won a si fi eyin mejeji ko ra won
awa okunrin awa o ma ronju
a o ni mo pe eko to ti ro lo tun pon
ani ko oloun shanu eyan ni ain
who is in the garden
eko la ti ri olosho to mu standing
ain ain arara ain arara
ese won o se je ni weekend rara o
irole ojo alamisi mo fi si o
igbayen lawon oku toti ku wale
lo so kini mi di carrot nikan je
emi lon fi oju drogba woo mo yen
to gba mi mu tan
lo so ara e di ronado momi lowo
ringtone ayinla omo wura lomu wa pe o
anu re lo se mi oo lo jen ba e da moran
ewa wo oyinbo to se koste
bo oyinbo ba ku re
ko ni sun re
awon oyinbo niba aye je baba o
won je a mo adelebo solomo ge
toba ro owo mu rubber mo onirin wo koko mo
won a si fi eyin mejeji ko ra won
awa okunrin awa o ma ronju
a o ni mo pe eko to ti ro lo tun pon
ani ko oloun shanu eyan ni ain
bin se wan ti keke omo yen lo ain
bi n se ti keke mo n ti keke ain
ti mo ti mu ogidiga ati baby oku
ain ain ain
omo yi fe pami ku ain ain ain
felele eyin mi fe kan o
egba mi o nigba tie yin mi fe re o
lo ba mumi ranti orin barri kan toni wipe o
nigba ton je igbadun e ta lo wi fun
ewa wo oyinbo to se koste
bo oyinbo ba ku re
ko ni sun re
awon oyinbo niba aye je baba o
won je a mo adelebo solomo ge
toba ro owo mu rubber mo onirin wo koko mo
won a si fi eyin mejeji ko ra won
awa okunrin awa o ma ronju
a o ni mo pe eko to ti ro lo tun pon
ani ko oloun shanu eyan ni ain
beko e
na free style things shey you get naso
shout out to mukaila
thanks for the inspiration
bless
dresan tiringbeku shoki
yepa yipo oka re omo yiko
small doctor
you dey follow god drag
what are you ba oloun po eee
Random Song Lyrics :
- jusqu'ici, tranquille - gino & rpz lyrics
- rencor - franco (mx) lyrics
- 2 cuori - doxa (ita) lyrics
- beautiful nightmare - beyazz lyrics
- gran azul - leo de la rosa lyrics
- agoonia/paroodia - seaduskuulekus lyrics
- fiori - lastanzadigreta lyrics
- the festival - necronomidol lyrics
- private party - machel montano lyrics
- carteiro - tião carreiro & pardinho lyrics