kokanmi - qdot lyrics
oni warapa ti rolu magun (kasa)
kokanmi, kokanmi, kokanmi, kokanmi
qdot ni oruko mi
mo mo pe mo mi le se n fi obo lomi
mi o le ori lo gun pe ibon o le ran mi
bibeli ni mo ni pelu quran
pelu kini bami to dun woroworo
eni fi oju di ina ina a jo
iya ibadan oya gbe agbo le ina
epo ogede won le yo mi
ma pe bi alafin oyo
werey ni won mo ma le won si aro
ma gbe won lo bi ti iya alaro
e fun mi hammer ki fo won lori ka
awon were awon motherf*ckers
ero dada ke to be esu lowe
e sun fun shigidi ko ma lo odo lo we
kilonje ko si ewe ko si egbo ni inu aiye
olorun ma je a ri ija aiye
shey kelebe
won ni pe
pe clients o soromo
pe iyawo yin se oloso
o sun yara landlord o
won fe mo idi abajo
tani baba alajo
e fi ile babalawo, ebo yin ma fo mo awo
won ni pe yahoo ni
won ni pe ashe ogun owo
won ni warapa ro lu magun
pe lagbaja bo oju korin
eni oyinbo o dun lenu mi
but local mi ja wo
oke kilamajaro so pe olump o ga
agbo ti aja a gbo ti eran
ewo ni ti agutan lori aga
won ni mo local mo n pa owo lo
omo folashade mo ti gbade lo
oyingbo le ma dun lenu mi
eyi ti nba sooh wole soyinka la ba yin tuu
e wa wo eleko to yan odi sho moimoi ori bo gan ni inu ewa agoyin
i don’t care if you like or not eni shishe lo ma pawo
shokoto ton jo leba ona ni oni re nbe ninu igbo
mo ti goke mo ti shishe lo ti fara to ja
mo ti je ki oyinbo to ja
omode ara ti wa dagba qdot o
omo ma le fi ede ja
eri oja ka ke to be esu lowe
e sun fun shigidi ko ma fi ojo lo we
kilonje ko si ewe ko si egbo ni inu aiye
olorun ma je a ri ija aiye
shey kelebe
won ni pe?
clients o soromo
pe iyawo yin she oloso
o sun yara landlord o
won fe mo idi abajo
tani baba alajo
e fi ile babalawo, ebo yin ma fo mo awo
won ni pe yahoo ni
won ni pe ashe ogun owo
won ni warapa ro lu magun
pe lagbaja bo oju korin
won ni oyinbo o dun lenu mi
but local mi gba wo
ori molade
eni fi oju di ina a jo
iya ibadan oya gbe agbo le ina
epo ogede o le yo mi
ma pe bi alafin oyo mi
Random Song Lyrics :
- pprt lpn - yung kurz lyrics
- bestgore girlfriend - ar7em lyrics
- cool off - chanel west coast lyrics
- fake - 3ple l lyrics
- аварійне світло - mykhal(михаль) lyrics
- gönderdim dişlerini (saygınlar) - takeda takahashi lyrics
- gwenu dan bysiau - datblygu lyrics
- closer - morgin madison, adam nazar & crimsen lyrics
- tạm biệt người từng thương - lil elsu lyrics
- thank us now - otm lyrics