giddem - naira marley lyrics
[intro]
yo*
big vibez
[verse 1]
if to say na me be you
if i see naira marley
ma ya sare se twale
i go ask baba for way
because igi imu jina s’ori
ọmọ ma ra ko to rin
sanmọ o le wa lẹ
ẹjẹ kan mo pe sanmọ o le wa lẹ
oju ra wọn lọ
o skingba kan ju kan lọ
a nọ gbe fun kan ju kan lọ
mo lo n bẹ bi kan ju kan lọ
[pre*chorus]
and it’s all on god (and it’s all on god)
that we are still on top
anything they like make them talk
ohun to ba wun ẹlẹnu lo le sọ
o ti ṣẹlẹ bayi
oti di agbo awọn werey bayi
wọn ti price kẹ ya ma bọ bayi
wọn ti price kẹ ya ma bọ bayi (h*llo)
o ti ṣẹlẹ bayi
oti di agbo awọn werey bayi
wọn ti price kẹ ya ma bọ bayi
wọn ti price kẹ ya ma bọ bayi (h*llo)
[chorus]
to ba funmi dollar, ma gba
to ba funmi naira, ma gba
pounds ma gba
to ba funmi l’owo, ma gba
giddem, giddem, gidden, giddem
giddem, giddem, gidden, giddem
giddem, giddem, gidden, giddem
giddеm, giddem, gidden, giddem
[verse 2]
ayеbo, ayeba
somebody call the popo
baba ibeji, iba jojo
t’emi ba k’ọri, k’iwọ ma jo
ayebo, ayeba
somebody call the popo
baba ibeji, iba jojo
temi ba k’ọri, k’iwọ ma jo
o le tẹ go mọlẹ, ma lọ t’agba mọlẹ
igo ma n ya yan l’ẹsẹ
agba ma surprise ẹ
basically agba ma n ya yan l’ẹnu
[pre*chorus]
and it’s all on god (and it’s all on god)
that we are still on top
anything they like make them talk
ohun to ba wun ẹlẹnu lo le sọ
o ti ṣẹlẹ bayi
oti di agbo awọn werey bayi
wọn ti price kẹ ya ma bọ bayi
wọn ti price kẹ ya ma bọ bayi (h*llo)
o ti ṣẹlẹ bayi
oti di agbo awọn werey bayi
wọn ti price kẹ ya ma bọ bayi
wọn ti price kẹ ya ma bọ bayi (h*llo)
[chorus]
to ba funmi dollar, ma gba
to ba funmi naira, ma gba
pounds ma gba
to ba funmi l’owo, ma gba
giddem, giddem, gidden, giddem
giddem, giddem, gidden, giddem
giddem, giddem, gidden, giddem
giddem, giddem, gidden, giddem
[outro]
big vibez
Random Song Lyrics :
- miało się nie udać - jan-rapowanie & nocny lyrics
- liquor stores - why nona lyrics
- амплуа (role) - ленинград (leningrad) lyrics
- we will rock you (fast) (live 1982) - queen lyrics
- chicken talk - gucci mane lyrics
- art of war - discrepancies lyrics
- yo! - ghet lyrics
- laser focus - tha god fahim lyrics
- molly whop - bruiser brigade lyrics
- giornate perse - latte lyrics