ayefele (feat. francis ajiboye) - king festus lyrics
festus bobo lo n ki
ayefele
rora maa se o
ayefele o eje ka rora se
aye gba pele kami a feso se
ika sa leeyan eyan sa ni ka o
ayefele o eje ka rora se
alabi imun nika
koma je a gboorun asebi o
eni ani kofeni loju
ata lofi senu
eni a ni ko kin ni lehin
egun lo lo fi sowo
eniyan buru oremi
ayefele oo we
se jeje ile aye ma gba jeje
ani koo se jeje
ile aye ma gba jeje
ayefele o e je ka rora see
aye gba pele kami a feso se
ika sa leeyan eyan sa ni ka o
ayefele o eje ka rora se
igbekele ninu eniyan
asan bansa ni o
olorun nikan loto farati
to’to gbokan le o
ma se gbara le’niyan
ayefele
ma se fo’kan tan eni kankan
aye gba jeje
ayefele ayefele ayefele oo
ayefele mo tun tenu mo
eje a maa feso se
ayefele o e je ka rora se
aye gba pele kami a feso se
ika se leeyan eeyan sa nika o
ayefele o eje ka rora se
festus bobo n pariwo
o ni ayefele
oni ma see gbara le’niyan
eniyan buru
omo eda le o
eniyan le’niyan maa je
eniyan ni ‘ka
eniyan kii s’olorun
mase gbara leniyan
oremi se jeje
oya se jeje
ajiboye n pariwo
oya se jeje
alalabi lo nki
ayefele
felefele
laye o oo
ayefele o e je ka rora se
eni te jo n je te jo n mun
too robi si o
o le j’oni tohun gangan
lofe se e nibi
ore m’eni toma barin
tori ayefele
festus bobo lo nki
ayefele o e je ka rora se
Random Song Lyrics :
- no fue tu culpa (intro) - martín valverde lyrics
- fácil - maldita nerea lyrics
- got my grind made up - ?henom lyrics
- oaff xp - decana lyrics
- remember the name - ghetto prince lyrics
- wow! - plusmacher lyrics
- you can think what you want - nox mc lyrics
- weekday - pino blanco lyrics
- dope sample - a$ap twelvyy lyrics
- a button on your blouse - drowners lyrics