tokini - ife ogunwumiju/oloriafrica lyrics
tokini tokeji lan la rugbo eba la jesi funro ta kete pon lan la mi lolo eba, eba bi eba, eba
oloriafrica aaaaa, grillo on the beat
oya
la bi la
we bi ewedu
ta bi ata
yo bi ewero
fo bi efo
yo bi ogbono
sho bi shoko
ba bi eba
oya
la bi la
we bi ewedu
ta bi ata
yo bi ewero
fo bi efo
yo bi ogbono
sho bi shoko
ba bi eba
to ba se pemi ni iwo ni
mba fa pa jo fa pa jo
bo ba se pemi ni iwo ni
mba fi ese jo fi ese jo
amope oni shibi
amope alata
amope olobe
sira wa sebe fun mi
amope oni shibi
amope alata
amope olobe
sira wa sebe fun mi
oya tokini tokeji
oya lan la rugbo
oya tokini tokeji
oya lan la rugbo
oya tokini tokini tokini tokini oya lan la lan la lan la
moni
la bi la
we bi ewedu
ta bi ata
yo bi ewero
fo bi efo
yo bi ogbono
sho bi shoko
ba bi eba
to ba se pemi ni iwo ni
mba fa pa jo fa pa jo
bo ba se pemi ni iwo ni
mba fi ese jo fi ese jo
aboki oni dollar
aboki oni malu
aboki ala ta
sira wa deliver fun mi
aboki oni dollar
aboki oni malu
aboki ala ta
sira wa deliver fun mi
oya tokini tokeji
oya lan la rugbo
oya tokini tokeji
oya lan la rugbo
oya tokini tokini tokini tokini oya lan la lan la lan la
moni
la bi la
we bi ewedu
ta bi ata
yo bi ewero
fo bi efo
yo bi ogbono
sho bi shoko
ba bi eba
tokini tokeji lan la rugbo eba la jesi funro ta kete pon lan la mi lolo eba, eba bi eba, eba
Random Song Lyrics :
- prime - mooghi, t.i. & cordae (2) lyrics
- ich schlucke gift - trip kid lyrics
- family reunion (español) - blink-182 lyrics
- стэйси (stacy) - w4xp3n lyrics
- don't let go - star boy lyrics
- 双人舞 - pas de deux - snh48 lyrics
- never (speed up) - enso (ensoxd) lyrics
- don't stop - sar4 xox0 lyrics
- lavender - ayyybroly lyrics
- spiderman in the flesh - matt maltese lyrics