kekere - dagrin lyrics
[intro]
won fe sere, won sope mo kere, won ma fe invite mi, ke, won ma sare, ah! won ni were, oo
[chorus: dagrin]
won sope mo kere, kekeker
labere kere, awon
to jepe won le sere bi mo se nsere
awon tojepe tiwon ba ri
akeke won ma sare, awon toba jepe
tiwon ba l’aroma won ni
were (were 4x) (2x)
[verse 1: dagrin]
won tun ti de, еmi mofe sanjo, emi mofe sanjo, bi obasanjo, kon sе iro, eni ti o ba ra iro kole ra oto, kati mo ibi to to gba kade mo ona t’oto, mo nsako tori mo l’awon to yii lowo, bi opolo se n sako niwaju elegusi dollar, gbogbo wa lafe je dollar, patapat ka wa lo se lodo mallam, taba kowo yen de, kawa ma f’owo yen cha*cha, inshort, gbogbo wa la fe, di millionaire
[chorus: dagrin]
won sope mo kere, kekeker
labere kere, awon
to jepe won le sere bi mo se nsere
awon tojepe tiwon ba ri
akeke won ma sare, awon toba jepe
tiwon ba l’aroma won ni
were (were 4x) (2x)
[verse 2: dagrin]
monday, tuesday and wednesday, thursday, titi di ojo jimoh, olowo laye mo, mo ni mo fe jemo, oluwa se mi lolowo, eni ba lomo, mi o ti lowo ,won ti nsare gbe rumour, itumo? abi e dayan mo?/ mo ti de, eti gbere, ok, womi dada, komo bimo se je, duala, biko, ejo talombe?, sukusuku bambam, eni t’oba wu ko be
[chorus: dagrin]
won sope mo kere, kekeker
labere kere, awon
to jepe won le sere bi mo se nsere
awon tojepe tiwon ba ri
akeke won ma sare, awon toba jepe
tiwon ba l’aroma won ni
were (were 4x) (2x)
[verse 3: dagrin]
emi to je pe, mi o n woju, uche, file!, gbasibe, aunty, bobo oya ki o ko mole, bere mole, mi o ni ki o boso sile, ma wo bose po to, won tobe, ok!, toba jebe, f’oro sile, move your body (body), shake your body (body), move to the dance floor, sugbon malo fi agbari gbari, ko gba’gidi, ko gba giri*giri/ talon gbemu?, baba oni waheed, i’m sorry, i’m in a hurry, don’t worry, mi o gbori, emi len sori?, a ki n ja kung fu but a je fufu, a nje dundu, a den, mu kunu, olu!
[chorus: dagrin]
won sope mo kere, kekeker
labere kere, awon
to jepe won le sere bi mo se nsere
awon tojepe tiwon ba ri
akeke won ma sare, awon toba jepe
tiwon ba l’aroma won ni
were (were 4x) (til the song fade)
Random Song Lyrics :
- part 1 - new light - lil depressd shit lyrics
- stop being greedy [woodstock 99] - dmx lyrics
- mariage 3 - t2r & minissia lyrics
- rite now! - autumn! lyrics
- born from fire - wolfheart lyrics
- the hand that rocks the cradle - k-dee lyrics
- весна вновь придёт (spring will come again) - drug flash lyrics
- human animal - haggard cat lyrics
- all i need - haddon cord lyrics
- nothing to me - swerzie lyrics