wo olúwa - congress musicfactory lyrics
wo olúwa
[ẹsẹ 1]
(okunrin)
wo oluwa lori ite re
oba awon oba ati oluwa awon oluwa
ijoba re wa t-ti lailai
agbara ati ola nla re duro t-ti
(gbogbo wa)
wo o joba t-ti lailai
eni ologo t’awa feran
lati ainipekun ko yi pada
ti o ti wa ti o nbe to si nbo wa
[akorin}
a gbe yin ga
ko s’eni t’ale fi o we
a gbe yin ga, bukun fun oruko mimo re
wo owo re
apapo eniyan mimo
a fi fun yin ni iyin giga
[ẹsẹ 2]
wo odo aguntan, omo olorun
oba to nsegun oba oun gbogbo
dun ipe re da araye lejo
j’ekamo pe oluwa alagbara njoba
[akorin}
a gbe yin ga
ko s’eni t’ale fi o we
a gbe yin ga, bukun fun oruko mimo re
wo owo re
apapo eniyan mimo
a fi fun yin ni iyin giga
[akorin}
a gbe yin ga
ko s’eni t’ale fi o we
a gbe yin ga, bukun fun oruko mimo re
wo owo re
apapo eniyan mimo
a fi fun yin ni iyin giga
a fi fun yin ni iyin giga
Random Song Lyrics :
- 06 am in bucharest - adflow lyrics
- servin - maximus prince lyrics
- black gainsbourg - tedax max lyrics
- get it - maximus prince lyrics
- sevirəm de - gülay zeynallı lyrics
- nar ağacı - aşıq samirə lyrics
- luckies in paris - david0mario lyrics
- yippee - aussie purser lyrics
- ne tikay - kyzivka lyrics
- rest in pain - owell mood (오웰무드) lyrics