èyin nìkan - congress musicfactory lyrics
èyin nìkan
[ẹsẹ]
pelu gbogbo okan mi ni mo juba re
ni gbogbo aye mi ni mo b’owo fun
olu aye mi, ni mo fun l’oun gbogbo
mo fi iyin fun eyin nikan
[ẹsẹ]
pelu gbogbo okan mi ni mo juba re
ni gbogbo aye mi ni mo b’owo fun
olu aye mi, ni mo fun l’oun gbogbo
mo fi iyin fun eyin nikan
[akorin]
f’eyin nikan, eyin nikan
mo fi iyin fun eyin nikan
eyin nikan, eyin nikan
mo fi iyin fun eyin nikan
[ẹsẹ]
pelu gbogbo okan mi ni mo juba re
ni gbogbo aye mi ni mo b’owo fun
olu aye mi, ni mo fun l’oun gbogbo
mo fi iyin fun eyin nikan
[akorin]
f’eyin nikan, eyin nikan
mo fi iyin fun eyin nikan
eyin nikan, eyin nikan
mo fi iyin fun eyin nikan
[akorin]
f’eyin nikan, eyin nikan
mo fi iyin fun eyin nikan
eyin nikan, eyin nikan
mo fi iyin fun eyin nikan
[ipari]
mo fi iyin fun eyin nikan
mo fi iyin fun eyin nikan
Random Song Lyrics :
- get out alive - tyler posey lyrics
- america forever - gretta ray lyrics
- выдумал (invented) - enty mike lyrics
- dopamin - young bego lyrics
- mom - blac carthi lyrics
- torito - millow, cocco lexa & gynebra lyrics
- внутри (inside) - pit (unique artist) lyrics
- solta o cabo da nau - leandro martins lyrics
- またぞろ一人 (matazoro hitori) - 高瀬大介 (takase daisuke) lyrics
- thashboi - flyana boss lyrics