
béèni yíò rí [adúrà] - congress musicfactory lyrics
béèni yíò rí [adúrà]
àmín, béèni yíò rí. àmín jé oro asé. gbogbo ìgbà tí a bá nse àmín sí adúrà nkan tán so ni wipe béèni yíò rí. agbé owó wa sókè. a sibùkún fúun yín. a bòwò fúun yín adúpé lówo yín ní torí eyín ni olórun tíó dára ati olúwa olótìto. eyín le dìwa mú, tí e sín tó wa sónà òt-tó ní gbogbo ìgbà atí fún odún pípé. eyín le mú wa lo sí ojó iwájú tó yè koro
a bùkún fúun orúko yín. efún wa ní ókùn àtagbára sí, láti lè se ifé yín. efún wa ní àse ati agbára ní gbogbo orílè àgbáyé. efún wa ní agbára láti oké orún wá, kí ogó le jé teyín nikán. afé kí gbogbo èdá álàyè wárírì níwájúu yín, kí wón gbée yín ga. a sì fé kí gbogbo ènìyàn le mopé, eyín ní olórun alágbára, oba gbogbo ayé, àti àsèdá gbogbo ènìyàn. ejé kí gbogbo ènìyàn mo títóbi agbára yín, afé kí wón mo isé árà àti isé iyánú tí énse
efún wa ní ore òfé láti lè ma gbéeyín sókè, láti bu olá fúun yín ní oun gbogbo tí àan se
Random Song Lyrics :
- vudú - lemu jake lyrics
- ne derse o - skapova lyrics
- hear my heart - dr. zed lyrics
- don't lesson me 2! - beemee lyrics
- backflips - liesaa lyrics
- do you miss me? - r rayliston lyrics
- starless night - nami kichi lyrics
- hittin' 3s - ilovemakonnen lyrics
- killing the time - in letter form lyrics
- l'amant de minuit - kulshenka lyrics