ayo - congress musicfactory lyrics
ayo
[ẹsẹ 1]
ayo re ni imole si okan mi
ayo re, kun mi, so mi di pipe
ayo re, ti le okunkun lo
mu mi rin ona re
ayo re
[akorin]
ni “waju re, l’opo ayo wa
mo kun f’ope, mo dupe t-ti lai
ko’rin iyin – iwo n’iye at’orin mi
okun mi; oluwa mi – layo mi
[ẹsẹ 2]
ayo re, mu eru wiwo fuye
ayo re, fun mi l’okun ija
ayo re, mu mi se oro re
lati rin ona re
ayo re
[akorin]
ni “waju re, l’opo ayo wa
mo kun f’ope, mo dupe t-ti lai
ko’rin iyin – iwo n’iye at’orin mi
okun mi; oluwa mi – layo mi
[ẹsẹ 3]
ayo re, f’itura s’okan mi
ayo re, fun mi n’ife ayika wa
ayo re, to mi si ojo re
lati rin ona re
ayo re
[akorin]
ni “waju re, l’opo ayo wa
mo kun f’ope, mo dupe t-ti lai
ko’rin iyin – iwo n’iye at’orin mi
okun mi; oluwa mi
[akorin]
ni “waju re, l’opo ayo wa
mo kun f’ope, mo dupe t-ti lai
ko’rin iyin – iwo n’iye at’orin mi
okun mi; oluwa mi
– layo mi
iwo la ayo mi
Random Song Lyrics :
- between us 2 - coach joey lyrics
- p.a.n.i.c! - yonaka lyrics
- preash vibes - dolphin friendly lyrics
- sálvame - sanju (esp) lyrics
- there won't be trumpets - suzanne henry lyrics
- resentment - ben jey lyrics
- heroes (live from coventry, 2021) - roger taylor lyrics
- умри - glebash lyrics
- živeti - patrisiya janković lyrics
- ジュピター (jupiter) - 岡田有希子 (yukiko okada) lyrics