lirikcinta.com
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

àmín! (yorùbá) - congress musicfactory lyrics

Loading...

àmín!

[akorin}
amin! be ni yio ri!
amin! gbo ase wa!
ki jobaa re de
oluwa jeki ife re di sise
ni sisiyin ati lailai
amin!

[akorin}
amin! be ni yio ri!
amin! gbo ase wa!
ki jobaa re de
oluwa jeki ife re di sise
ni sisiyin ati lailai
amin!

[ ẹsẹ 1]
iwo l’olorun gbogbo eda
oun’gbogbo wa labe ase re
mu’dajo re wa s’orile ede
jeki awon olododo duro

[akorin}
amin! be ni yio ri!
amin! gbo ase wa!
ki jobaa re de
oluwa jeki ife re di sise
ni sisiyin ati lailai
amin!

[akorin}
amin! be ni yio ri!
amin! gbo ase wa!
ki jobaa re de
oluwa jeki ife re di sise
ni sisiyin ati lailai
amin!

[ẹsẹ 2]
ran oro re si gbogbo aye
j’eka awon ayanfe gbo ipe re
se wani okan awon eniyan mimo
k’aye leri gbogbo ogo re

[akorin}
amin! be ni yio ri!
amin! gbo ase wa!
ki jobaa re de
oluwa jeki ife re di sise
ni sisiyin ati lailai
amin!

[akorin}
amin! be ni yio ri!
amin! gbo ase wa!
ki jobaa re de
oluwa jeki ife re di sise
ni sisiyin ati lailai
amin!

[ipari]
ki jobaa re de
oluwa jeki ife re di sise
ni sisiyin ati lailai
amin!

Random Song Lyrics :

Popular

Loading...