oluranlowo - by singers lyrics
Loading...
[verse 1]
angeli bi eniyan
eniyan bi angeli o
oluranlowo kan
t’o nu omije mi nu
t’o gba’so iya lara mi
baba…
ran won simi o
ran won simi o
[verse 2]
awa nwo oju re fun iranlowo
mase je k’awa lo lofo…
kosi eni wa o wa
to lo lowo ofo
mase je kawa lo lofo
[chorus]
eniyan tio waye ti kori iranlowo
owa ye asan ni o…
ran won simi o ran won simi o
alejo oloore tio ran mi lowo
ran won simi o ran won simi o
alejo alaanu tio gbemi dide
Random Song Lyrics :
- white canvas - rise to fall lyrics
- desperado slowed - eduardo luzquiños lyrics
- american dad - mo troper lyrics
- outro último desejo - clarisse grova lyrics
- heart thinks - nora collins & frank legeay lyrics
- high school sweetheart - tenille arts lyrics
- hush freestyle - low kidd lyrics
- red lips - the parakeets lyrics
- deirdre - hey pam! lyrics
- marc jacobs - acid souljah lyrics