lirikcinta.com
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

olúmọ - brymo lyrics

Loading...

mò n lọ sáké mo fẹ́ lọ rọ́jọ̀gbọ́n o
mò n lọ sábéòkúta mo fé lọ rí
ọmọ ṣóyínká

oṣóyinká ooooo
oṣóyinká
oṣóyinká ooooo

bẹ lọ sówu
bẹ bá rárẹ̀mú o
bẹ bá rí bába ìyábọ̀, ẹ bá mi ki
ẹbọra òwu
ẹbọra òwu ooooo
ẹbọra òwu, eh
ẹbọra òwu ooooo

bẹ lọ sábẹ́òkúta ìlú olúmọ
bẹ bá ráláké ẹ bá mi ki

Random Song Lyrics :

Popular

Loading...