digital bonus track - asa lyrics
oru si lekun,
i wanna have some talk, with you-o
nitori rẹ mo sẹ lola
nitori rẹ mo sẹ sogẹ
nitori rẹ mo sẹ ra moto
mo wo lẹ, mo boluwa mi soro
nitori rẹ mo sẹ wa laiye
nitori rẹ mo sẹ wa so sara
nitori re moji lowuro
mo wo aye mi lo de ye ya
aa aho ha ha a ha
iba fi ele
iba fi eledua
aa ho ho a ho
mo mo le ye
mo boluwa mi soro
nitori re mo sẹ gbo
iroyin ayo
lai so owo
lai si nkan kan
i ya oni layo la o o
boluwa se wi be na lori
oh oh o wi kpe kim ma se beru
so aho ho a ho a a ho
aa aho ha ha a ha
iba fi ele
iba fun eledua
mo wo le
mo boluwa mi soro
ninu ikpon ju
ninu i damu
be emi ba gbo ro
ma wo lẹ ma boluwa mi soro
bẹ emi o lẹ yọ
ba aye ba fi oju dẹ mi
be emi oni ile
ma wo le ma boluwa mi soro
aa aho ha ha a ha
iba fi ele
iba fun eledua
iba o o o o
mo wo le ye
mo boluwa mi soro
o o o mi
ninu ikpon ju
ninu idamu
be mi ba gbo ro
ma wo le ma boluwa mi soro
mo o ni foju sunku mo o o o
aye lo ja, orun ni ile
ẹni a fi ba mi
iba o o o
Random Song Lyrics :
- no pueo para - yung beef lyrics
- goodbye it's 1987 - microdisney lyrics
- change is gonna come - kelly joyce lyrics
- kendimden geçerim - murat yılmazyıldırım lyrics
- don't say that you miss me - mannis lyrics
- pāvilosta - liepājas brāļi lyrics
- do you mind - ripsi winelover lyrics
- koczownicy pod marketem - sebastian minga lyrics
- te amo - gastón y su grupo santa fe lyrics
- the life, the pary, the scene - hey vanity lyrics