lirikcinta.com
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

olufisinmi - adegoke adedamola lyrics

Loading...

olufisinmi fi sinmi s’okan mi
mase je k’ayanfe re
ko ri idibaje
bi ida ba tile nbo o
f’eje re o fi gbe mi ro
bi iji ba ti le nfe
f’eje re o fi gbe mi ro

iwo leni tin pami mo kuro ninu ewu gbogbo
o ki yo je ki ese mi ko ye (rara)
gbani gbani tingbani laigbeje
gbani gbani lojo ogun le
gba ti aye banfe f*gbara re gbe mi ro o baba mi oke yi
f’ iye apa re bo mi o

olufisinmi fi sinmi s’okan mi
mase je k’ayanfe re
ko ri idibaje
bi ida ba tile nbo o
f’eje re o fi gbe mi ro
bi iji ba ti le nfe
f’eje re o fi gbe mi ro

gba mi lowo ajakale arun
gba mi lowo ogun aye pata pata
tile tile mi
tomo tomo mi
eje jesu ni mo pase sori yin
bi ida ba tile nbo ( bi ida ba n bo)
f’eje re o fi gbe mi ro
bi iji ba ti le nfe (bi iji nfe o)
f’eje re o fi gbe mi ro
peace be still…..

Random Song Lyrics :

Popular

Loading...