happy people - aṣa lyrics
o òré mi láídé
níbo ló dà l’ójó sat-rday yìí
hmmm… wón se party níhìn o
l’ókè súnáà léhìn kùlé àwon làtí
ànkárá la dá
kòstúmù la wò
kosé l’afi gbóyàn sókè
bàtà mí ti ready
ànkárá la dá
kòstúmù la wò
kosé l’afi gbóyàn sókè
bàtà mí ti ready
oh we’re happy people
and that’s who we are
we’re having fun
we’re the children of the sun
oh we’re happy people
and that’s who we are
we don’t care
we’re the children of the sun
o òré mi laide
níbo ló kàn l’ójó sunday yìí
hmmm… wón gbéyàwó níhin o
l’ókè pópó légbe ilé àwon toyeeb
ànkárá la dá
kòstúmù la wò
kosé l’afi gbóyàn sókè
bàtà mí ti ready
ànkárá la dá
gèlè búlúù la wò
kosé l’afi gbóyàn sókè
bàtà mí ti ready
oh we’re happy people
and that’s who we are
we’re having fun
we are the children of the sun
oh oh we happy people
and that’s who we are
we don’t care
we are the children of the sun
oh oh we happy people
and that’s who we are
we’re having fun
we are the children of the sun
oh oh we happy people
and that’s who we are
oh we don’t care
we are the children of the sun
oh oh we happy people
and that’s who we are now
oh we don’t care
we are the children of the sun
Random Song Lyrics :
- make me mad - surf lyrics
- change - hadi herz lyrics
- fuckboy - rj payne lyrics
- just for you - sax in the house lyrics
- thương thầm - ricky star lyrics
- nuvah? - ize lyrics
- sadness - magg dylan lyrics
- try me! - anarchy-anxient lyrics
- these are my friends - fantastic negrito lyrics
- nothing lastz - biglu91 lyrics