awé - aṣa lyrics
Loading...
awe ibo lo lo ka
ta n fi wao ka
ibi o ba lo je a mo
anti to n gbe le i tosi
o wa o wa le yi
ati o jo meta atabo
o wi kpe o o
o loyun fun o
oyun oshu meji
o loyun fun o
wahidi omo sekina
omo muyina
omo mohammed
anti ton loyun fun o
o to bi e l’omo/i wo iwo na
anti to loyun fun o
o to bi e l’omo
o bi ‘mo oh oh
o bi ‘mo
ire lo ni mu, ese
irun ori, iwo dudu
omo kpu pa ba wo lo se ri
wahidi omo sekina
omo muyina
omo mohammed
ewa wo ja la fin
oba ejigbo
atabo, atako
won ja la fin oba
la fin oba
wahidi omo muyina ni
omo sekina
o foju mi ri mabo
mabo ni le, mabo loko
mabo l’eko
mama to bi mama re
ni mama mi
emi na bi te mi
moo ntomo lowo
f’omo l’oyon
ma ko tire bami
abo oro lan so f’omo
luabi, to ba de nu re a do n di n di
din din
Random Song Lyrics :
- i loved her - big daddy papi chulo lyrics
- gestation begins - pathology lyrics
- long nights of summer - elmer gantry's velvet opera lyrics
- one step behind - grebo lyrics
- droga, acordei o meu dog - natu rap lyrics
- pagaidām - jumprava lyrics
- kehtolaulu hirtetylle - juice leskinen lyrics
- compilation - rad (la radance) lyrics
- that sound - bombargo lyrics
- wer klopfet an - nena lyrics