lirikcinta.com
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

power must change hands - 9ice lyrics

Loading...

intro
máà lékè wọn
máà lékè wọn
máà lékè wọn*
(it’s protunez on the beat)
verse
mo dò ṣí bàtà tí lékè odò o
ẹjá arọ ń bẹ nísàlẹ odò o
má f’ẹjá bọ’rí, gbé mi lékè wọn
ìgbàgbọ mí tí mú mi lára dá
gbogbo àgbára tí yí po padà, ahh
mo tí lékè wọn
pre*chorus
now, i’m grinding, my enemies are crawling
some dey beside me, but never see me coming
my train is nonstop, don’t ever try to cross me
ah, mo tí lékè wọn
chorus
i know, power must change hands right now
they know, ẹlẹmi lo má last right now
b’okun o rú, b’ọsa o rú
ìwọ là má lékè wọn
b’okun o rú, b’ọsa o ru
àwa là má lékè wọn
ọmọ to ń pá’dán, idán gan*gan idán
ọmọ to ń pá’wó, ìwọ lolè ṣána
ọmọ to ń pá’dán, idán gan*gan idán
ọmọ to ń pá’wó, ìwọ lolè ṣana
verse
mo kọ tá, mo kòpée, ọtá ń jẹ
pé ò gbọdọ fọ’hùn
ọmọ tó ń pá’wó, tọ ń ṣiṣẹ́
ò gbọdọ májẹ ìgbádùn
ojú ẹnì má lá, dandan ní arí ìyọnu
áìfaila ọjọ, t’ọjọ bálá, máa làá
pre*chorus
now, i’m grinding, my enemies are crawling
some dey beside me, but never see me coming
my train is nonstop, don’t ever try to cross me
ahh, mo tí lékè wọn
chorus
i know (má lékè wọn), power must change hands right now (ìyá wọn, bàbá wọn)
they know, ẹlẹmi lo má last right now
b’okun o rú (b’owó ru), b’ọsa o rú (b’owó ru)
ìwọ là má lékè wọn (à má lékè wọn)
b’okun o rú, b’ọsa o rú
àwa là má lékè wọn (eh*eh*eh*ehh)
ọmọ tó ń pá’dán (ọmọ), idán gan*gan idán (ko má pá’dán lọ)
ọmọ to ń pá’wó, ìwọ lolè ṣana
ọmọ to ń pá’dán, idán gan*gan idán
ọmọ to ń pá’wó, ìwọ lolè ṣanaa

Random Song Lyrics :

Popular

Loading...